Olddies
Àwon Omo aláìgboràn pò n'Ilé Ìwé,
Won kò f'Etí sílè sóhun t'Olùkó ńkó won.
Chorus: Dòdò àti Ráìsì kògbodò kojá, wón á jeun-jeun, wón á gbòdo roboto.
Isé, isé, ìyen kìń se tiwon,
Eré, Eré, ìyen ni tiwon..
Chorus: Dòdò àti Ráìsì kògbodò kojá, wón á jeun-jeun, wón á gbòdo roboto
Translation.
Rebellious children abound in schools,
They will not obey their teacher's instructions.
Chorus: They are so addicted to eating rice and fried plantain that they get zero in their studies effortlessly.
They hate hardwork,
They are too playful.
Chorus: They are so addicted to eating rice and fried plantain that they get zero in their studies effortlessly
Comments
Post a Comment